Awuyewuye ti suyọ lori fidio kan to gba ori ayelujara kan eyi to se afihan Timi Agbale ilu Ede, Ọba Munirudeen Adesola Lawal, Laminisa Kinni to tẹriba, to si tun kunlẹ ki Emir ilu Ilorin ...
Ajagunfẹyinti kan, to tun kopa ninu ogun abẹle Naijiria, Nasiru Salami, ti ṣalaye bi iya ṣe n jẹ awọn ajagunfẹyinti ni Naijiria. Baba ẹni ọdun mẹrindinlọgọrin naa sọ pe ...
“Mo fi Aláàfin hàn án niì” (I showed him the colour of the palace), he told me on the symbolic implication of what he did. Oba Adeyemi also saw Yorubaland as his constituency. In the ...